1. A. Ọba 2:31 YCE

31 Ọba si wi fun u pe, Ṣe gẹgẹ bi o ti wi ki o si kọlù u, ki o si sin i, ki iwọ ki o le mu ẹ̀jẹ alaiṣẹ̀ kuro lọdọ mi ati kuro lọdọ ile baba mi, ti Joabu ti ta silẹ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 2

Wo 1. A. Ọba 2:31 ni o tọ