1. A. Ọba 2:38 YCE

38 Ṣimei si wi fun ọba pe, Ọrọ na dara, gẹgẹ bi oluwa mi ọba ti wi, bẹ̃ gẹgẹ ni iranṣẹ rẹ yio ṣe. Ṣimei si gbe Jerusalemu li ọjọ pupọ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 2

Wo 1. A. Ọba 2:38 ni o tọ