1. A. Ọba 2:7 YCE

7 Ṣugbọn ki o ṣe ore fun awọn ọmọ Barsillai, ara Gileadi, ki o si jẹ ki nwọn ki o wà ninu awọn ti o jẹun lori tabili rẹ: nitori bẹ̃ni nwọn ṣe tọ̀ mi wá nigbati mo sá kuro niwaju Absalomu, arakunrin rẹ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 2

Wo 1. A. Ọba 2:7 ni o tọ