1. A. Ọba 20:10 YCE

10 Benhadadi si ranṣẹ si i, o si wipe, Ki awọn oriṣa ki o ṣe bẹ̃ si mi, ati jù bẹ̃ lọ pẹlu bi ẽkuru Samaria yio to fun ikunwọ fun gbogbo enia ti ntẹle mi.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 20

Wo 1. A. Ọba 20:10 ni o tọ