12 O si ṣe, nigbati Benhadadi gbọ́ ọ̀rọ yi, bi o ti nmuti, on ati awọn ọba ninu agọ, li o sọ fun awọn iranṣẹ rẹ̀ pe, Ẹ tẹ́gun si ilu na.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 20
Wo 1. A. Ọba 20:12 ni o tọ