24 Nkan yi ni ki o si ṣe, mu awọn ọba kuro, olukuluku kuro ni ipò rẹ̀, ki o si fi olori-ogun si ipò wọn.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 20
Wo 1. A. Ọba 20:24 ni o tọ