1. A. Ọba 20:27 YCE

27 A si ka iye awọn ọmọ Israeli, nwọn si pese onjẹ, nwọn si lọ ipade wọn: awọn ọmọ Israeli si dó niwaju wọn gẹgẹ bi agbo ọmọ ewurẹ kekere meji: ṣugbọn awọn ara Siria kún ilẹ na.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 20

Wo 1. A. Ọba 20:27 ni o tọ