40 Bi iranṣẹ rẹ si ti ni iṣe nihin ati lọhun, a fẹ ẹ kù. Ọba Israeli si wi fun u pe, Bẹ̃ni idajọ rẹ yio ri: iwọ tikararẹ ti dá a.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 20
Wo 1. A. Ọba 20:40 ni o tọ