1. A. Ọba 22:10 YCE

10 Ọba Israeli ati Jehoṣafati, ọba Juda joko olukulùku lori itẹ́ rẹ̀, nwọn wọ̀ aṣọ igunwa wọn ni ita ẹnu-bode Samaria, gbogbo awọn woli na si nsọtẹlẹ niwaju wọn.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 22

Wo 1. A. Ọba 22:10 ni o tọ