1. A. Ọba 22:17 YCE

17 On si wipe, Mo ri gbogbo Israeli tukakiri lori awọn oke bi agutan ti kò ni oluṣọ: Oluwa si wipe, Awọn wọnyi kò ni oluwa, jẹ ki nwọn ki o pada olukuluku si ile rẹ̀ li alafia.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 22

Wo 1. A. Ọba 22:17 ni o tọ