1. A. Ọba 22:28 YCE

28 Mikaiah si wipe, Ni pipada bi iwọ ba pada bọ̀ li alafia, njẹ Oluwa kò ti ipa mi sọ̀rọ. O si wipe, Ẹ gbọ́, ẹnyin enia gbogbo!

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 22

Wo 1. A. Ọba 22:28 ni o tọ