1. A. Ọba 22:31 YCE

31 Ṣugbọn ọba Siria paṣẹ fun awọn olori-kẹkẹ́ rẹ̀, mejilelọgbọn, ti o ni aṣẹ lori kẹkẹ́ rẹ̀ wipe, Máṣe ba ẹni-kekere tabi ẹni-nla jà, bikoṣe ọba Israeli nikan.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 22

Wo 1. A. Ọba 22:31 ni o tọ