1. A. Ọba 22:39 YCE

39 Ati iyokù iṣe Ahabu, ati gbogbo eyi ti o ṣe, ati ile ehin-erin ti o kọ́, ati gbogbo ilu ti o tẹ̀do, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Israeli?

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 22

Wo 1. A. Ọba 22:39 ni o tọ