1. A. Ọba 3:13 YCE

13 Ati eyiti iwọ kò bere, emi o fun ọ pẹlu ati ọrọ̀ ati ọlá: tobẹ̃ ti kì yio si ọkan ninu awọn ọba ti yio dabi rẹ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 3

Wo 1. A. Ọba 3:13 ni o tọ