1. A. Ọba 3:17 YCE

17 Ọkan ninu wọn si wipe, Jọwọ, oluwa mi, emi ati obinrin yi ngbe ile kan; emi si bi ọmọ ni ile pẹlu rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 3

Wo 1. A. Ọba 3:17 ni o tọ