1. A. Ọba 4:24 YCE

24 Nitori on li o ṣe alaṣẹ lori gbogbo agbègbe ni iha ihin odò, lati Tifsa titi de Gasa, lori gbogbo awọn ọba ni iha ihin odò: o si ni alafia ni iha gbogbo yi i kakiri.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 4

Wo 1. A. Ọba 4:24 ni o tọ