1. A. Ọba 4:34 YCE

34 Ẹni pupọ si wá lati gbogbo orilẹ-ède lati gbọ́ ọgbọ́n Solomoni; ani lati ọdọ gbogbo awọn ọba aiye, ti o gburo ọgbọ́n rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 4

Wo 1. A. Ọba 4:34 ni o tọ