1. A. Ọba 6:35 YCE

35 O si yá awọn kerubu, ati igi-ọpẹ, ati itanna eweko si ara wọn: o si fi wura bò o, eyi ti o tẹ́ sori ibi ti o gbẹ́.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 6

Wo 1. A. Ọba 6:35 ni o tọ