1. A. Ọba 6:7 YCE

7 Ile na, nigbati a nkọ́ ọ, okuta ti a ti gbẹ́ silẹ ki a to mu u wá ibẹ li a fi kọ́ ọ, bẹ̃ni a kò si gburo mataka, tabi ãke, tabi ohun-elo irin kan nigbati a nkọ́ ọ lọwọ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 6

Wo 1. A. Ọba 6:7 ni o tọ