29 Ati lara alafo ọ̀na arin ti mbẹ lagbedemeji ni aworan kiniun, malu, ati awọn kerubu wà; ati lori ipade eti, ijoko kan wà loke: ati labẹ awọn kiniun, ati malu ni iṣẹ ọṣọ́ wà.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 7
Wo 1. A. Ọba 7:29 ni o tọ