1. A. Ọba 7:38 YCE

38 O si ṣe agbada idẹ mẹwa: agbada kan gbà to òji iwọn Bati: agbada kọ̃kan si jẹ igbọnwọ mẹrin: lori ọkọ̃kan ijoko mẹwẹwa na ni agbada kọ̃kan wà.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 7

Wo 1. A. Ọba 7:38 ni o tọ