50 Ati ọpọ́n, ati alumagaji-fitila, ati awo-koto, ati ṣibi, ati awo turari ti wura daradara; ati agbekọ wura, fun ilẹkun inu ile, ibi mimọ́-julọ, ati fun ilẹkun ile na, ani ti tempili.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 7
Wo 1. A. Ọba 7:50 ni o tọ