9 Gbogbo wọnyi jẹ okuta iyebiye gẹgẹ bi iwọn okuta gbigbẹ́, ti a fi ayùn rẹ́ ninu ati lode, ani lati ipilẹ de ibori-oke ile, bẹ̃ si ni lode si apa agbala nla.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 7
Wo 1. A. Ọba 7:9 ni o tọ