1. A. Ọba 8:13 YCE

13 Nitõtọ emi ti kọ́ ile kan fun ọ lati mã gbe inu rẹ̀, ibukojo kan fun ọ lati mã gbe inu rẹ̀ titi lai.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:13 ni o tọ