1. A. Ọba 8:16 YCE

16 Lati ọjọ ti emi ti mu Israeli, awọn enia mi jade kuro ni Egipti, emi kò yàn ilu kan ninu gbogbo ẹyà Israeli lati kọ́ ile kan, ki orukọ mi ki o le mã gbe inu rẹ̀: ṣugbọn emi yàn Dafidi ṣe olori Israeli, awọn enia mi.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:16 ni o tọ