1. A. Ọba 8:18 YCE

18 Oluwa si wi fun Dafidi baba mi pe, Bi o tijẹpe o wà li ọkàn rẹ lati kọ́ ile kan fun orukọ mi, iwọ ṣe rere ti o fi wà li ọkàn rẹ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:18 ni o tọ