1. A. Ọba 8:2 YCE

2 Gbogbo awọn ọkunrin Israeli si pe ara wọn jọ si ọdọ Solomoni ọba ni ajọ ọdun ni oṣu Etanimu, ti iṣe oṣu keje.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:2 ni o tọ