26 Njẹ nisisiyi, Ọlọrun Israeli, jẹ ki a mu ọ̀rọ rẹ ṣẹ, emi bẹ̀ ọ, ti iwọ ti sọ fun iranṣẹ rẹ, Dafidi baba mi.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8
Wo 1. A. Ọba 8:26 ni o tọ