1. A. Ọba 8:4 YCE

4 Nwọn si gbe apoti-ẹ̀ri Oluwa wá soke, ati agọ ajọ enia, ati gbogbo ohun-elo mimọ́ ti o wà ninu agọ ani nkan wọnni ni awọn alufa ati awọn ọmọ Lefi gbe goke wá.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:4 ni o tọ