42 Nitoriti nwọn o gbọ́ orukọ nla rẹ, ati ọwọ́ agbára rẹ, ati ninà apa rẹ; nigbati on o wá, ti yio si gbadura si iha ile yi;
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8
Wo 1. A. Ọba 8:42 ni o tọ