52 Ki oju rẹ ki o le ṣi si ẹ̀bẹ iranṣẹ rẹ, ati si ẹ̀bẹ Israeli enia rẹ, lati tẹtisilẹ si wọn ninu ohun gbogbo ti nwọn o ke pè ọ si.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8
Wo 1. A. Ọba 8:52 ni o tọ