1. A. Ọba 8:56 YCE

56 Ibukún ni fun Oluwa ti o ti fi isimi fun Israeli enia rẹ̀, gẹgẹ bi gbogbo eyiti o ti ṣe ileri: kò kù ọ̀rọ kan ninu gbogbo ileri rere rẹ̀ ti o ti ṣe lati ọwọ Mose, iranṣẹ rẹ̀ wá.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:56 ni o tọ