1. A. Ọba 8:9 YCE

9 Kò si nkankan ninu apoti-ẹri bikoṣe tabili okuta meji, ti Mose ti fi si ibẹ ni Horebu nigbati Oluwa ba awọn ọmọ Israeli dá majẹmu, nigbati nwọn ti ilẹ Egipti jade.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:9 ni o tọ