1. A. Ọba 9:19 YCE

19 Ati gbogbo ilu iṣura ti Solomoni ni, ati ilu kẹkẹ́ rẹ̀, ati ilu fun awọn ẹlẹsin rẹ̀, ati eyiti Solomoni nfẹ lati kọ́ ni Jerusalemu, ati ni Lebanoni, ati ni gbogbo ilẹ ijọba rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 9

Wo 1. A. Ọba 9:19 ni o tọ