1. A. Ọba 9:7 YCE

7 Nigbana ni emi o ké Israeli kuro ni ilẹ ti emi fi fun wọn; ati ile yi, ti mo ti yà si mimọ́ fun orukọ mi li emi o gbe sọnù kuro niwaju mi; Israeli yio si di owe ati ifiṣẹsin lãrin gbogbo orilẹ-ède.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 9

Wo 1. A. Ọba 9:7 ni o tọ