1. Sam 1:7 YCE

7 Bi on iti ma ṣe bẹ̃ lọdọdun, nigbati Hanna ba goke lọ si ile Oluwa, bẹni Peninna ima bà a ni inu jẹ; nitorina ama sọkun, kò si jẹun.

Ka pipe ipin 1. Sam 1

Wo 1. Sam 1:7 ni o tọ