1. Sam 10:12 YCE

12 Ẹnikan lati ibẹ na wá si dahùn, o si wipe, ṣugbọn tani baba wọn? Bẹ̃li o si wà li owe, Saulu wà ninu awọn wolĩ pẹlu?

Ka pipe ipin 1. Sam 10

Wo 1. Sam 10:12 ni o tọ