21 On si mu ki ẹya Benjamini sunmọ tosi nipa idile wọn, a mu idile Matri, a si mu Saulu ọmọ Kiṣi: nigbati nwọn si wá a kiri, nwọn kò si ri i.
Ka pipe ipin 1. Sam 10
Wo 1. Sam 10:21 ni o tọ