1. Sam 10:25 YCE

25 Samueli si sọ ìwa ijọba fun awọn enia na. O si kọ ọ sinu iwe, o si fi i siwaju Oluwa. Samueli si rán gbogbo enia na lọ, olukuluku si ile rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Sam 10

Wo 1. Sam 10:25 ni o tọ