1. Sam 11:1 YCE

1 NAHAṢI ara Ammoni si goke wá, o si do ti Jabeṣi-Gileadi: gbogbo ọkunrin Jabeṣi si wi fun Nahaṣi, pe, Ba wa da majẹmu, awa o si ma sìn ọ.

Ka pipe ipin 1. Sam 11

Wo 1. Sam 11:1 ni o tọ