1. Sam 13:7 YCE

7 Omiran ninu awọn Heberu goke odo Jordani si ilẹ Gadi ati Gileadi. Bi o ṣe ti Saulu, on wà ni Gilgali sibẹ, gbogbo enia na si nwariri lẹhin rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Sam 13

Wo 1. Sam 13:7 ni o tọ