1. Sam 14:32 YCE

32 Awọn enia sare si ikogun na, nwọn si mu agutan, ati malu, ati ọmọ-malu, nwọn si pa wọn sori ilẹ: awọn enia na si jẹ wọn t'ẹjẹ t'ẹjẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:32 ni o tọ