1. Sam 14:39 YCE

39 Nitoripe gẹgẹ bi Oluwa ti wà ti o ti gbà Israeli là bi o tilẹ ṣepe a ri i lara Jonatani ọmọ mi, nitõtọ yio kú. Ṣugbọn ninu gbogbo enia na, kò si ẹniti o da a lohùn.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:39 ni o tọ