1. Sam 14:52 YCE

52 Ogun na si le si awọn Filistini ni gbogbo ọjọ Saulu: bi Saulu ba ri ẹnikan ti o li agbara, tabi akikanju ọkunrin, a mu u sọdọ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Sam 14

Wo 1. Sam 14:52 ni o tọ