13 Samueli si tọ Saulu wá: Saulu si wi fun u pe, Alabukún ni ọ lati ọdọ Oluwa wá: emi ti ṣe eyi ti Oluwa ran mi.
Ka pipe ipin 1. Sam 15
Wo 1. Sam 15:13 ni o tọ