16 Samueli si wi fun Saulu pe, Duro, emi o si sọ eyi ti Oluwa wi fun mi li alẹ yi. On si wi fun u pe, Ma wi.
Ka pipe ipin 1. Sam 15
Wo 1. Sam 15:16 ni o tọ