1. Sam 15:24 YCE

24 Saulu si wi fun Samueli pe, Emi ti ṣẹ̀: nitoriti emi ti re ofin Oluwa kọja, ati ọ̀rọ rẹ̀: nitori emi bẹ̀ru awọn enia, emi si gbà ohùn wọn gbọ́.

Ka pipe ipin 1. Sam 15

Wo 1. Sam 15:24 ni o tọ