1. Sam 15:26 YCE

26 Samueli si wi fun Saulu pe, emi kì yio tun yipada pẹlu rẹ mọ nitoriti iwọ ti kọ̀ ọ̀rọ Oluwa, Oluwa si ti kọ̀ iwọ lati ma jẹ ọba lori Israeli.

Ka pipe ipin 1. Sam 15

Wo 1. Sam 15:26 ni o tọ