1. Sam 15:33 YCE

33 Samueli si wipe, Gẹgẹ bi idà rẹ ti sọ awọn obinrin di alaili ọmọ, bẹ̃ gẹgẹ ni iya rẹ yio si di alaili ọmọ larin obinrin. Samueli si pa Agagi niwaju Oluwa ni Gilgali.

Ka pipe ipin 1. Sam 15

Wo 1. Sam 15:33 ni o tọ