1. Sam 15:4 YCE

4 Saulu si ko awọn enia na jọ pọ̀ o si ka iye wọn ni Telaimu, nwọn si jẹ ogun ọkẹ awọn ọkunrin ogun ẹlẹsẹ, pẹlu ẹgbarun awọn ọkunrin Juda.

Ka pipe ipin 1. Sam 15

Wo 1. Sam 15:4 ni o tọ